Jump to content

Kehinde Bankole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kehinde Bankole
Ọjọ́ìbíKehinde Bankole
27 Oṣù Kẹta 1985 (1985-03-27) (ọmọ ọdún 39)
Ogun State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Mass Communication, Olabisi Onabanjo University
Iléẹ̀kọ́ gígaOlabisi Onabanjo University
Iṣẹ́Actress, model, TV host
Ìgbà iṣẹ́2003–present
Awardsrevelation of the year award at 2009 Best of Nollywood Awards

Kehinde Bankole jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà, àwòkọ́ṣe àti olùgbàléjò. Ó bẹ̀rẹ̀ssí ní kópa nínú ìṣe tíátà nínu eré superstory, tí Wálé Adénúgà.[1] [2] Ó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà. Ó ní ìbejì, tí ó má ń kópa nínú eré ní ẹ̀kànkàn.

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà . Ó ní arábìnrin ìbejì kan tí ó má ń ṣeré lẹ́kọ̀ọ̀kan. Ó kàwé ní Tunwase Nursery and Primary School, Ikeja. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìbáraenisọ̀rọ̀ ọ̀pọ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Olabisi Onabanjo ṣùgbọ́n ó sinmi lati dojú kọ iṣẹ́ àwòṣe rẹ̀ ní ọdún 2004.[3]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Fíìmù / Ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
Ọdún Iṣẹ́ Ojúṣe Ọ̀rọ̀
2011 Perfect Church Film
Two Brides and a Baby Pewa
2012 The Meeting Kikelomo
2013 Awakening Zainab
Façade
2014 Render to Caesar
October 1 Miss Tawa
2015–present Desperate Housewives Africa Kiki Obi Television
2016–present Dinner
2018 Grace
No Budget
2018 Bachelor's Eve
2019 The Set Up
2020 Dear Affy Affy
Mama Drama Kemi
Finding Hubby
2021 Love Castle
2021 Country Hard
2022 Blood Sisters Yinka Ademola
2022 Sistá Sistá
2023 Kizazi Moto: Generation Fire Moremi (voice) Episode: "Moremi"

Àmì-ẹ̀yẹ àti yiyan fún àmì-ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Fíìmù Èsì Ìtọ́ka
2014 ELOY Awards TV Actress of the Year (Super Story) N/A Wọ́n pèé [4]
2020 2020 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Lead role –English Dear Affy Wọ́n pèé [5]
2021 Abuja International Film Festival Outstanding Female Actor Love Castle Wọ́n pèé [6]
2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Actress in A Drama Dear Affy Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ [5]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Yinka, Ade (14 April 2021). "Actress, Kehinde Bankole reveals why she ignores her fans". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 15 March 2022. 
  2. "Acting involves brainwork, not only good looks — Kehinde Bankole". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 May 2022. Retrieved 19 July 2022. 
  3. https://www.manpower.com.ng/people/15982/kehinde-bankole
  4. "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014. 
  5. 5.0 5.1 "Behold hot steppers and winners at BON awards 2020". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 December 2020. Retrieved 11 October 2021. 
  6. "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.