Kenneth Dike

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Kenneth Dike (17 December 1917 – 26 October 1983[1]) je was a Nigerian ojogbon akoitan ara Naijiria ati eni akoko to di Giwa Yunifásítì ìlú Ìbàdàn. Nigba ti Ogun Abele Naijiria bere o ko lo si Harvard University, Boston ni Amerika.

O pari eko ni Fourah Bay College, Sierra Leone ati ni awon yunifasiti ni Durham ati London.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]