Kesaoleboga Molotsane

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kesaoleboga Molotsane
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kẹẹ̀jọ osù kìńní ọdún 1992 (Ọgbọ̀n ọdún)
Sport
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Erẹ́ìdárayáEré Sísá ọ̀nà jíjìn

Kesaoleboga Molotsane tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kínní ọdún 1992 jẹ́ olùsáré ọ̀nà jińjìn ti orílẹ̀ ède South Africa kan. Ní ọdún 2019, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà ní 2019 IAAF World Cross Country Championship tí ó wáyé ní Aarhus, Denmark. [1] O pari pẹ̀lú ipò kejìlélógójì. [1]

Ní ọdún 2017, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbààwọn obìnrin àgbà ní 2017 IAAF World Cross Country Championship tí ó wáyé ní Kampala, Uganda. O pari pẹ̀lú ipò karùndínlógójì. [2] Ní ọdún kannáà, ó tún kópa nínú 5000 metres ti àwọn obìnrin tiSummer Universiade ní ọdún 2017 tí ó wáyé ní Taipei, Taiwan. O pari pẹ̀lu ipò kẹẹ̀sán pẹ̀lú dídára fún ra rẹ̀ ti 16:01.76. [3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named senior_women_race_iaaf_world_cross_country_2019
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named senior_women_race_iaaf_world_cross_country_2017
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named women_5000m_summer_universiade_2017