Jump to content

Kim Fields

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kim Fields
Fields in 2019
Ọjọ́ìbíKim Victoria Fields
12 Oṣù Kàrún 1969 (1969-05-12) (ọmọ ọdún 55)
New York City, New York, U.S.
Orúkọ mírànKim Fields Freeman
Ẹ̀kọ́Pepperdine University
Iṣẹ́Actress, director
Ìgbà iṣẹ́1977–present
Gbajúmọ̀ fúnThe Facts of Life, Living Single
Olólùfẹ́
Johnathon Franklin Freeman (m. 1995–2001)

Christopher Morgan (m. 2007)
Àwọn ọmọ2
Parent(s)Chip Fields (mother)
Àwọn olùbátanAlexis Fields (sister)

Kim Victoria Fields (ọjọ́ìbí May 12, 1969) ni òṣeré àti olúdarí ètò tẹlifísàn ará Amẹ́ríkà. Fields gbajúmọ̀ fún ìseré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Dorothy "Tootie" Ramsey nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn NBC The Facts of Life (1979–1988), àti gẹ́gẹ́ bíi Regine Hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn Fox, Living Single (1993–1998). Fields ni ọmọ Chip Fields tí òhun náà jẹ̀ òṣeré àti olùdarí, àti ẹ̀gbọ́n Alexis Fields.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]