Kirenga Saphine
Appearance
Saphine Kirenga | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Saphine Kirenga 25 September Rwanda |
Orílẹ̀-èdè | Rwandan |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–present |
Olólùfẹ́ | Sebera Eric (2015) |
Saphine Kirenga jẹ́ obìnrin osere ara Rùwándà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà. Ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù bíi The Chains of Love, Dreams, Sakabaka, Rwasibo, Seburikoko, Urugamba àti The Secret of Happiness.[1] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ìlera.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "THINK ABOUT SAPHINE'S MOST IMPORTANT PLAYER TO BRING NEWS WITH BOY". celebzmagazine. Archived from the original on 3 August 2021. Retrieved 16 October 2020.
- ↑ "Team Mutoni". Mutoni TV. Retrieved 16 October 2020.
Àwọn ìtakùn Ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Rwanda international movie awards Archived 2021-01-19 at the Wayback Machine.
- Kuri uyu wa Gatanu abakunzi ba filime baramurikirwa iyitwa Archived 2021-11-14 at the Wayback Machine.