Jump to content

Końskowola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòran Konskowola látòkèrè
Coat of Końskowola

Abule kan ni ila-oorun gusu ile Polandi ni o n je Końskowola (IPA [kɔɲskɔ'vɔla]). O wa laarin Pulawi ati Kuro.

Itumo ti a le fun Konskowola ni Ife Esin (Horse's Will) sugbon oruko re gan-an wa lati ara Wola - orisii abule kan, oruko eni ti o si ni in ni Jan z Konina (Jan Koninski, Joonu ti Koni). Odun 1442 ni won se akiyesi oruko ti a n pe ni Koninskawola yii.

Ni nnkan bii senturi kerinla (XIV) ni won da abule yii sile ni abe Witowska Wola. Won wa yi oruko re pada si Koniiskawola ni senturi kokandinlogun (XIX).