Koji orange
Àdàkọ:Speciesbox/hybrid name | |
---|---|
Koji orange fruits | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/CitrusC. leiocarpa
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/CitrusCitrus leiocarpa | |
Forms | |
| |
Synonyms | |
Osan koji (Citrus leiocarpa), ti atun pé ni smooth-fruited orange ni ede geesi , bingyul ni Korean, 光橘 (guang ju), 柑 子 (gan zi), ati 日本土柑 (ri ben tu gan) ni Chinese, and コウジ (kōji) ni Japanese, je eya Citrus ti o tan mo Japan.[1] specific epithet (leiocarpa) wa lati Greek leios (= smooth) ati karpon (= fruit). O je taxonomical Citrus aurantium.[2]
Ipin kiri re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Yato si Japan, a máan gbin ni US ati ni apa ile East Asia titi to fi kàn South Korea ati China.[2]
Àpèjúwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eso yìí jé oblate ni awo, diẹ lo fi ri roboto, o tun tan yóò ,o tun Kere gan pẹlu eso pupo , ati nitori kikere rẹ ati eso pupo yìí ni a ki fi gbin fún ohun ilo eniyan pipo. O Saba maa pọn ni Ọktoba titi wo Novemba,won ti gbin eso yi lati 1900. O ti le je eleso jan. Igi re ní ẹka ni won ba pẹlu ade tó gbọrọ pẹlu trunk kekere . Awo ewe re se green loju dada ati o ri roboto ni awo.[1]
Genetik
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Citrus leiocarpa je eso ti a mo ti o ti ara oríṣi koji (seed parent) ati osan tachibana (pollen parent, Citrus tachibana). Genotype re jọ mo ti komikan ati toukan varieties.[3]
Orisi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Citrus leiocarpa f. monoembryota, je orisi citrus leiocarpa, ti Chozaburo Tanaka sa àpèjúwe rẹ ri. O ti koko gbagbo wipe o fe fi ara pe osan koji ati wipe asiri Ti tu pe ara koji ati kishu ni o ti jade (pollen parent) and kishu (seed parent).[3] Ni ede Chinese ,a npe ni alled 駿河柑子 (jun he gan zi) ati won tun npe スルガユコウ (suruga yukō) ati 駿河柚柑 (suzuzukan) ni Japanese.
O tun lewo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn Atokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "CRC3147". citrusvariety.ucr.edu. Retrieved 18 January 2021.
- ↑ 2.0 2.1 "Citrus leiocarpa hort. ex Tanaka". www.gbif.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 18 January 2021.
- ↑ 3.0 3.1 Shimizu, Tokurou; Kitajima, Akira; Nonaka, Keisuke; Yoshioka, Terutaka; Ohta, Satoshi; Goto, Shingo; Toyoda, Atsushi; Fujiyama, Asao et al. (30 November 2016). "Hybrid Origins of Citrus Varieties Inferred from DNA Marker Analysis of Nuclear and Organelle Genomes". PLOS ONE 11 (11): e0166969. Bibcode 2016PLoSO..1166969S. doi:10.1371/journal.pone.0166969. PMC 5130255. PMID 27902727. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=5130255.
- ↑ "M.M.P.N.D. - Sorting Citrus names part1". www.plantnames.unimelb.edu.au. Retrieved 12 February 2021.