Konstantinos Demertzis
Appearance
Konstantinos Demertzis (Gíríkì: Κωνσταντίνος Δεμερτζής; 1876, Athens – 1936, Athens) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Greece. Ó jẹ́ alákòóso àgbà lati Oṣù kọkànlạ ọdún 1936 sí Oṣù kẹrin ọdún 1936. Demertzis di olóògbé nípasẹ̀ ààrùn ọkàn ní Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kẹrin ọdún 1936.