Kris draper
Born | 24 Oṣù Kàrún 1971 Toronto, Ontario, Canada | ,
Height Weight |
5 ft 10 in (1.78 m) 188 lb (85 kg; 13 st 6 lb) |
Position | Centre |
Shoots | Left |
Pro clubs | Winnipeg Jets Detroit Red Wings |
Ntl. team | Àdàkọ:Ih |
NHL Draft | 62nd overall, 1989 Winnipeg Jets |
Pro career | 1989 – 2011 |
Kristopher Bruce "Kris" Draper (tí wọ́n ní oṣù kàrún-un ọdún 1971) sí Canada jẹ́ ọ̀kan lára Eléré Agbá Hockey, tí ó sì jẹ́ Olùdarí Àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́ fún àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀dé àti Olùrànlọ́wọ́ gbogbogbò fún Detroit Red Wings, tí ẹgbẹ́ rẹ̀ sí gbà Hockey fún sáà mẹ́tàdínlógún ní gbogbo ìgba tó fí gbà Hockey.
Draper tí gbà Àmi ẹ̀yẹ Stanley Cup ní ẹ̀ẹ̀mẹrin ọ̀tọ́tọ̀ ní Detroit, o tún jẹ́ eni tí ó gbà Àmi ẹ̀yẹ Frank J. Sells, ó sí tí gbà bọ́ọ̀kù sí àwọ̀n ni ìgbà ọgọ́rùn-ún ní igbà tí ó ń gbà Hockey pẹ̀lú Red Wings. Draper jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí ó ní òkìkí ní Grind Line] ní Detroit, ti àwọn akẹgbẹ́ rẹ sí jẹ́ Kirk Maltby àti Joe Kocur tabi Darren McCarty. Àwọn Eré ìparí 222 rẹ̀ẹ jẹ́ kí ó wà ní ipo kẹwàá ní Atoókọ ti àwọn Olùdarí ìṣirò NHL #Playoff.
Àwọn iṣé lẹ́yìn eré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́yìn ìfẹ̀yìntì Draper nídì iṣé hockey, Wọ́n gbàá sí iṣé Red Wings gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára Òṣìṣẹ́ ọ́fìsì.Ó ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀ rí bí olùrànlọwọ pàtàkì sí olùṣàkóso gbogbogbò, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ken Holland.
Ní ipò yìí, Draper ṣiṣẹ́ ní pẹ́kípẹ́kí pẹ̀lú ẹgbẹ́ ìṣàkóso Detroit, láti ṣe ìrànlọ́wọ́ ìgbéléwọ̀n fún àwọn eléré Hockey fún àwọn tí wọn sẹ̀sẹ̀ bè àti àwọn tí wọn tì dì àgbà ọ̀jẹ̀ tàbí ọ̀jọ̀gbọ́n nínú eré Hockey.
Wọn yóò béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ láti pèsè ìgbéwòlè nípa àwọn ìṣòwò tí ó pọ́jú àti àwọn ìforúkọsílẹ aṣojú ọ̀fẹ́, àti pèsè òye sí àwọn yíyan tí ó pọ̀jù ní àkópamọ́ NHL lọ́dọọdún.
Ni osù keje, ọdún 2019, Draper ní ìgbéga sí ipò Olùdarí àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀ dé, eyi tí Steve Yzerman tí ó jẹ́ akẹgbẹ re náà wà ní ipò olùṣàkóso gbogbogbò tuntun, lẹ́yìn tí Tyler Wright kúrò lọsí Edmonton. Ní oṣù keje náà ní ọdún 2023, Ó tún rí ìgbéga sí Red wing gẹ́gẹ́ bí olùrànlọwọ Kejì sí Olùdarí gbogbogbò.[1]
Igbé ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Draper àti aya rere ní ọmọ Obìnrin Méjì, Kenndi àti Kamryn, oẹ̀lú ọkùnrin kàn, Keinan. Kienan wà l'ára àwọn tí Saginaw Spirit yàn ní round kẹjọ ní Ontario Hockey League ní ọdún 2018.[2][3] He played for the Chilliwack Chiefs of the British Columbia Hockey League during the 2020–2021 season, and currently plays for the Michigan Wolverines.[4][5] Kienan was drafted in the seventh round, 187th overall, overall by the Detroit Red Wings in the 2020 NHL Entry Draft.[6]
Ere òkèrè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Medal record | |||
---|---|---|---|
Adíje fún Canada | |||
Men's ice hockey | |||
World Championships | |||
Wúrà | 2003 Finland | ||
Fàdákà | 2005 Austria | ||
World Cup of Hockey | |||
Wúrà | 2004 Canada | ||
World Junior Championships | |||
Wúrà | 1991 Canada | ||
Wúrà | 1990 Finland |
Draper participated in eight international tournaments for Canada:
- 1990 World Junior Ice Hockey Championships
- 1991 World Junior Ice Hockey Championships
- 2000 IIHF World Championship
- 2001 IIHF World Championship
- 2003 IIHF World Championship
- 2004 World Cup of Hockey
- 2005 IIHF World Championship
- 2006 Winter Olympics
Career statistics
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Regular season and playoffs
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Regular season | Playoffs | |||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Season | Team | League | GP | G | A | Pts | PIM | GP | G | A | Pts | PIM | ||
1987–88 | Don Mills Flyers Midget AAA | MTHL | 40 | 35 | 32 | 67 | 46 | — | — | — | — | — | ||
1988–89 | Canadian National Team | Intl | 60 | 11 | 15 | 26 | 16 | — | — | — | — | — | ||
1989–90 | Canadian National Team | Intl | 62 | 12 | 22 | 34 | 44 | — | — | — | — | — | ||
1990–91 | Ottawa 67's | OHL | 39 | 19 | 42 | 61 | 35 | 17 | 8 | 11 | 19 | 20 | ||
1990–91 | Moncton Hawks | AHL | 7 | 2 | 1 | 3 | 2 | — | — | — | — | — | ||
1990–91 | Winnipeg Jets | NHL | 3 | 1 | 0 | 1 | 5 | — | — | — | — | — | ||
1991–92 | Moncton Hawks | AHL | 61 | 11 | 18 | 29 | 113 | 4 | 0 | 1 | 1 | 6 | ||
1991–92 | Winnipeg Jets | NHL | 10 | 2 | 0 | 2 | 2 | 2 | 0 | 0 | 0 | 0 | ||
1992–93 | Moncton Hawks | AHL | 67 | 12 | 23 | 35 | 40 | 5 | 2 | 2 | 4 | 18 | ||
1992–93 | Winnipeg Jets | NHL | 7 | 0 | 0 | 0 | 2 | — | — | — | — | — | ||
1993–94 | Adirondack Red Wings | AHL | 46 | 20 | 23 | 43 | 49 | — | — | — | — | — | ||
1993–94 | Detroit Red Wings | NHL | 39 | 5 | 8 | 13 | 31 | 7 | 2 | 2 | 4 | 4 | ||
1994–95 | Detroit Red Wings | NHL | 36 | 2 | 6 | 8 | 22 | 18 | 4 | 1 | 5 | 12 | ||
1995–96 | Detroit Red Wings | NHL | 52 | 7 | 9 | 16 | 32 | 18 | 4 | 2 | 6 | 18 | ||
1996–97 | Detroit Red Wings | NHL | 76 | 8 | 5 | 13 | 73 | 20 | 2 | 4 | 6 | 12 | ||
1997–98 | Detroit Red Wings | NHL | 64 | 13 | 10 | 23 | 45 | 19 | 1 | 3 | 4 | 12 | ||
1998–99 | Detroit Red Wings | NHL | 80 | 4 | 14 | 18 | 79 | 10 | 0 | 1 | 1 | 6 | ||
1999–00 | Detroit Red Wings | NHL | 51 | 5 | 7 | 12 | 28 | 9 | 2 | 0 | 2 | 6 | ||
2000–01 | Detroit Red Wings | NHL | 75 | 8 | 17 | 25 | 38 | 6 | 0 | 1 | 1 | 2 | ||
2001–02 | Detroit Red Wings | NHL | 82 | 15 | 15 | 30 | 56 | 23 | 2 | 3 | 5 | 20 | ||
2002–03 | Detroit Red Wings | NHL | 82 | 14 | 21 | 35 | 82 | 4 | 0 | 0 | 0 | 4 | ||
2003–04 | Detroit Red Wings | NHL | 67 | 24 | 16 | 40 | 31 | 12 | 1 | 3 | 4 | 6 | ||
2005–06 | Detroit Red Wings | NHL | 80 | 10 | 22 | 32 | 58 | 6 | 0 | 0 | 0 | 6 | ||
2006–07 | Detroit Red Wings | NHL | 81 | 14 | 15 | 29 | 58 | 18 | 2 | 0 | 2 | 24 | ||
2007–08 | Detroit Red Wings | NHL | 65 | 9 | 8 | 17 | 68 | 22 | 3 | 1 | 4 | 10 | ||
2008–09 | Detroit Red Wings | NHL | 79 | 7 | 10 | 17 | 40 | 8 | 1 | 0 | 1 | 0 | ||
2009–10 | Detroit Red Wings | NHL | 81 | 7 | 15 | 22 | 28 | 12 | 0 | 0 | 0 | 16 | ||
2010–11 | Detroit Red Wings | NHL | 47 | 6 | 5 | 11 | 12 | 8 | 0 | 1 | 1 | 2 | ||
NHL totals | 1,157 | 161 | 203 | 364 | 790 | 222 | 24 | 22 | 46 | 160 |
International
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Team | Event | Result | GP | G | A | Pts | PIM | |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
1990 | Canada | WJC | Àdàkọ:Goca | 7 | 0 | 2 | 2 | 4 | |
1991 | Canada | WJC | Àdàkọ:Goca | 7 | 1 | 3 | 4 | 0 | |
2000 | Canada | WC | 4th | 3 | 1 | 0 | 1 | 0 | |
2001 | Canada | WC | 5th | 7 | 1 | 2 | 3 | 0 | |
2003 | Canada | WC | Àdàkọ:Goca | 9 | 0 | 3 | 3 | 10 | |
2004 | Canada | WCH | Àdàkọ:Goca | 5 | 2 | 2 | 4 | 2 | |
2005 | Canada | WC | Àdàkọ:Sica | 9 | 0 | 2 | 2 | 6 | |
2006 | Canada | OG | 7th | 6 | 0 | 0 | 0 | 0 | |
Junior totals | 14 | 1 | 5 | 6 | 4 | ||||
Senior totals | 39 | 4 | 9 | 13 | 18 |
Àmì Ẹ̀yẹ àti Àmì ìyìn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Award | Year | |
---|---|---|
NHL | ||
Stanley Cup | 1997, 1998, 2002, 2008 | |
Frank J. Selke Trophy | 2004 | [7] |
Ẹ tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Khan, Ansar (July 5, 2023). "Kris Draper promoted to Red Wings’ assistant GM, continues role as scouting director". MLive.com. Retrieved July 5, 2023.
- ↑ "Son of Wings' Draper selected in OHL draft". The Detroit News. April 7, 2018. https://www.detroitnews.com/story/sports/nhl/red-wings/2018/04/07/son-wings-draper-selected-ohl-draft/33640315/.
- ↑ "Kris Draper Bio". Detroit Red Wings. April 7, 2018. Retrieved April 7, 2018.
- ↑ "Chilliwack Chiefs add player with NHL bloodlines". Chilliwack Chiefs. February 20, 2020. https://www.theprogress.com/sports/chilliwack-chiefs-add-player-with-nhl-bloodlines/.
- ↑ "Kienan Draper Bio". Michigan Athletics. Retrieved October 21, 2022.
- ↑ St. James, Helene (October 7, 2020). "Detroit Red Wings pick Kris Draper's son in Round 7". Detroit Free Press. https://www.freep.com/story/sports/nhl/red-wings/2020/10/07/2020-nhl-draft-detroit-red-wings-nine-picks-day-2-live-updates/5908237002/.
- ↑ "Frank J. Selke Trophy winners". National Hockey League. 2010-06-04. Retrieved 2010-06-04.
External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Kris draper |
Preceded by Jere Lehtinen |
Winner of the Frank J. Selke Trophy 2004 |
Succeeded by Rod Brind'Amour |
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- 1971 births
- Canadian ice hockey centres
- Detroit Red Wings personnel
- Detroit Red Wings players
- Frank Selke Trophy winners
- Ice hockey players at the 2006 Winter Olympics
- Living people
- Olympic ice hockey players for Canada
- Ottawa 67's players
- Ice hockey people from Toronto
- Stanley Cup champions
- Winnipeg Jets (1979–1996) draft picks
- Winnipeg Jets (1979–1996) players