Krischka Stoffels
Ìrísí
Krischka Stoffels | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Krischka Stoffels Windhoek, Namibia |
Orílẹ̀-èdè | Namibian |
Iṣẹ́ | Director, writer, screen writer, cinematographer, editor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Krischka Stoffels jẹ́ olùdarí eré àti agbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàmíbíà. Krischka ti ṣiṣẹ́ lóri ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó fi mọ́ Gesie in die glas àti Tjiraaa.[1] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn àti olóòtú fíìmù.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Women excel in Namibian film making". The Villager. Archived from the original on 6 March 2019. Retrieved 11 October 2020.