Krystal Okeke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Krystal Okeke
Ọjọ́ìbíChicago, Illinois, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaGovernors State University
Prairie State College
Iṣẹ́
  • Model
  • journalist
  • philanthropist
Ìgbà iṣẹ́2012–present

Krystal Okeke jẹ́ oníróyìn àti mọ́dẹ́lì ọmọ Nàìjíríà.[1][2] Òun ni olùdásílè ẹgbẹ́ America Kids Multicultural Organisation àti Miss and Mrs America Nation beauty pageant.[3][4]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bíi Krystal sì Chicago, Illinois ni orílẹ̀ èdè USA. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Taraba. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Taraba, ìyá rẹ si jẹ́ ọmọ Anambra.[5] Ó lo ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ aiyé rẹ ni Kaduna níbi tí ó gbé fún ọdún mẹ́rìndínlógún kí ó tó padà sí USA.[6] Ní ọdún 2017, ó gboyè nínú mass communication láti Praire State college kí ó tó padà tún wà gboyè nínú ìròyìn láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Governors State University.[7]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Krystal nífẹ̀ẹ́ sì iṣẹ́ mọ́dẹ́lì, ó sì ti bẹ̀rẹ̀ láti bíi ọmọ ọdún márùn-ún. Ní ọdún 2012, nígbà tí ó si wà ní Nàìjíríà ni ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ mọ́dẹ́lì gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́. Ní ọdún 2016, ó gboyè Miss Illinois USA, leyin ti o ti gbìyànjú láti gba ni ẹ mẹta tẹ́lẹ̀. Ó ṣe aṣojú fún ìpínlè Illinois ni Miss USA Universal ni ọdún 2016, ó sì gbé ipò kẹta.[8] Ní ọdún 2017, ó dá America Kids Multicultural World Organization ati Miss America Nation beauty pageant sílẹ̀.[9][10] Ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 2019, ó gbà ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí asoju fún àwọn Ọlọpa ní Nàìjíríà.[11]


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Nda-Isaiah, Solomon (30 March 2016). "Nigeria: Miss Illinois Shows Love to Less-Privileged On Easter Day". Archived from the original on 30 March 2016. https://web.archive.org/web/20160330155124/https://allafrica.com/stories/201603300115.html. Retrieved 13 January 2020. 
  2. Nda-Isaiah, Solomon (8 January 2020). "Kaduna State Police Wives Association Empower Widows". Leadership Newspaper. Retrieved 13 January 2020. 
  3. "Chicago Multicultural Kids Fashion Show preview". WLS-TV. 17 June 2018. Retrieved 13 January 2020. 
  4. "Miss & Mrs America Nation 2019". Pageant Planet. Retrieved 15 January 2020. 
  5. "Nigerian Born US Beauty Queen Krystal Okeke Dazzles In Fulani Attire Photo shoot After Abuja Visit". Modern Ghana. 28 June 2017. Retrieved 13 January 2020. 
  6. Kopycinski, Gary (2 May 2016). "Sitting Down With Krystal Okeke, Park Forest's Own Ms. Illinois USA Universal 2016". eNews Park Forest. Retrieved 13 January 2020. 
  7. Jo, Daniel (26 May 2017). "Krystal Okeke Bags World Class Beauty Queen Award (Photos)". Information Nigeria. Retrieved 13 January 2020. 
  8. "Nigerian Beauty, Krystal Okeke, Mz Illinois Dazzles At Ms USA Universal Contest, Named State Ambassador". The Nigerian Voice. 12 August 2016. Retrieved 13 January 2020. 
  9. "150 Kids Showcased Fashion At Chicago Halloween And MulticulturalShow Hosted By Krystal Okeke". Modern Ghana. 13 January 2020. Retrieved 13 January 2020. 
  10. "2019 Miss and Mrs America Nation; and Kids Multicultural Runway". Briyanakelly.com. 15 April 2019. Archived from the original on 13 January 2020. Retrieved 13 January 2020. 
  11. "American Born Nigerian Beauty Queen Hosts Nigeria Top Police Commissioners In Chicago, Receives Police Ambassadorial Medal Of Honour (Photos)". Igbere TV. 30 October 2019. Retrieved 13 January 2020.