Kuda Bank
Ìrísí
Industry | Banking |
---|
Kuda,tí a tún mọ̀ sí Kuda Technologies, jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ tó níṣe pẹ̀lú ètò ìṣúná ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti U.K. Babs Ogundeyi àti Musty Mustapha ni ó dáa sílẹ̀ ní ọdún 2019.[1][2][3]
Kuda wà lára ọ̀kan nínú méje àwọn ilé-iṣẹ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ ìbẹ̀rẹ̀pèpẹ̀ Áfíríkà WEF ní ọdún 2021.
Iye ìwọ̀n ìfowópamọ́ Kuda ni $500 million, ó sì ti lé kọja $90 million láti ọwọ́ olùdókòwò bí i Target Global àti Valar Ventures.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Inside Kuda Bank’s playbook for banking every African". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-13. Retrieved 2021-06-17.
- ↑ Harrison, Polly Jean (2021-04-17). "Top African Challenger Banks Helping the Unbanked Through Mobile Services". The Fintech Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-17.
- ↑ "Kuda Bank: Broadening banking access with innovation". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-12. Retrieved 2022-02-05.
- ↑ Lunden, Ingrid (2 August 2021). "Kuda, the African challenger bank, raises $55M at a $500M valuation". Retrieved 11 April 2022.