Kurt Gödel
Kurt Gödel | |
---|---|
Fáìlì:Kurt Gödel.jpg Kurt Gödel | |
Ìbí | Brno, Moravia, Austria-Hungary | Oṣù Kẹrin 28, 1906
Aláìsí | January 14, 1978 Princeton, New Jersey, U.S. | (ọmọ ọdún 71)
Pápá | Mathematics, Mathematical logic |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Institute for Advanced Study |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Vienna |
Doctoral advisor | Hans Hahn |
Doctoral students | None |
Ó gbajúmọ̀ fún | Gödel's incompleteness theorems, Gödel's completeness theorem, the consistency of the Continuum hypothesis with ZFC |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Albert Einstein Award (1951) |
Religious stance | Theist |
Signature |
Kurt Gödel (Pípè nì Jẹ́mánì: [kʊʁt ˈɡøːdl̩] ( listen); April 28, 1906, Brno, Moravia – January 14, 1978, Princeton, New Jersey, USA) je onimomathematiki, onimo-oye ati onimo-ogbon omo ile Austria. Gege bi enikan to se pataki larin awon onimo-ogbon, Godel ni ipa to se koko lori ironu sayensi ati imo-oye ni orundun 20, asiko ti opolopo eniyan bi Bertrand Russell, A. N. Whitehead ati David Hilbert n sefilole lilo ogbon ati ironusi akojopo lati ṣèyé àwon ifilole mathematiki.
Godel je olokiki fun awon aronuse tikolepari, to tejade ni 1931 ni igba to je omo odun 25, odun kan pere leyin igba to pari eri olukoni ni Yunifasiti ilu Vienna. Aronuse tikolepari eyi to gbajumoju so pe fun irukiru sistemu alagbekale ton...
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |