Jump to content

Kurt Gödel

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Kurt Godel)
Kurt Gödel
Fáìlì:Kurt Gödel.jpg
Kurt Gödel
Ìbí(1906-04-28)Oṣù Kẹrin 28, 1906
Brno, Moravia, Austria-Hungary
AláìsíJanuary 14, 1978(1978-01-14) (ọmọ ọdún 71)
Princeton, New Jersey, U.S.
PápáMathematics, Mathematical logic
Ilé-ẹ̀kọ́Institute for Advanced Study
Ibi ẹ̀kọ́University of Vienna
Doctoral advisorHans Hahn
Doctoral studentsNone
Ó gbajúmọ̀ fúnGödel's incompleteness theorems, Gödel's completeness theorem, the consistency of the Continuum hypothesis with ZFC
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síAlbert Einstein Award (1951)
Religious stanceTheist
Signature

Kurt Gödel (Pípè nì Jẹ́mánì: [kʊʁt ˈɡøːdl̩]  ( listen); April 28, 1906, Brno, Moravia – January 14, 1978, Princeton, New Jersey, USA) je onimomathematiki, onimo-oye ati onimo-ogbon omo ile Austria. Gege bi enikan to se pataki larin awon onimo-ogbon, Godel ni ipa to se koko lori ironu sayensi ati imo-oye ni orundun 20, asiko ti opolopo eniyan bi Bertrand Russell, A. N. Whitehead ati David Hilbert n sefilole lilo ogbon ati ironusi akojopo lati ṣèyé àwon ifilole mathematiki.

Godel je olokiki fun awon aronuse tikolepari, to tejade ni 1931 ni igba to je omo odun 25, odun kan pere leyin igba to pari eri olukoni ni Yunifasiti ilu Vienna. Aronuse tikolepari eyi to gbajumoju so pe fun irukiru sistemu alagbekale ton...