Kusitiiki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Cushtic

Kusitiiki

Kí á to lè ri Chustic gẹ́gẹ́ bí ìdílé kan ó ní ṣe pé kí á pápọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ ìsọ̀rí èdè yòókù, díẹ̀ nínú wọn dá hàn yàtọ̀ láàrín ara wọn; Àwọn kan ṣe àfihàn tí ó dádúró tí ó ṣi yàtò láàrín ẹ̀ka egbẹ́. Ó ṣì ṣúnmọ́ atodefimọ èdè. Díẹ̀ laarin àwọn àgbà ẹgbẹ́ odẹ ni Kenya lo ń ṣọ Yaaku. Àwọn ẹgbẹ́ mééfèfà jo ni nǹkan kan to jọ jẹ àjọni lórí ẹ̀kọ́ nípa ayé to dúró lórí aṣàmì tí ó wa ní ìsàlẹ̀, ìlà Òòrùn Cushitic to wà lórí òkè ati èyí to wa ní ìlà Òòrùn to wa nílẹ̀, Dullay àti Yaakuni nǹkan tí wọn fi se àárin dipo kí a ka lábẹ́ ìlà Òòrùn ẹwọ́n Cushitic.

(1) Cushitic to wa ní Àríwá kún fún èdè eyọkan, Badawi/Beja (1,148), tí á ń ṣọ ní agbègbè to farapẹ́ ìpín ti Sudan, Egypt àti Eriterea.

(2) Cushitic to wa ní àringbùngbùn jẹ mọ èdè Àgaw, ó jẹ ẹgbẹ́ ti a ṣe atúnmọ̀ rẹ̀ lórísìírìsí ni Àríwá ìlà Òòrùn Ethiopia àti Kwara lápapọ̀ 1,000), Xamtunga (80), Awngi (490), àti díẹ̀ lórìṣìírìsí tó rún

(3) Ai ba ìgbà mu fún Burji, Cushitic tó wà ní ìlà òòrùn tún mún ìpàdé ìṣùpọ̀ àhánnupè. Àwọn sọ̀rọ̀sọ̀sọ̀ ń gbé ní orí òkè tí wọn ń ṣọ Burji wa ní Àríwá Kenya àwọn ẹgbẹ́ náà ní Burji (87) Sidamo (1,500) àti Kambata Halìyya ẹgbẹ̀rún kan. Àwọn Cushitic ìlà Òòrùn ní ẹka ẹgbẹ́ mẹta.

(i) Àwọn ẹ̀ka ẹgbẹ́ Àríwá wọn dúró fún saho (144) àti Afari (1,200)

(ii) Àwọn ẹ̀ka ẹgbẹ́ Oromoid kún fún Orísìírìsí Ojúlówó Oromo (13, 960) tí wọ́n tí sọ̀rọ̀ lati Odò Tana ní kenya si ìpààlà sudan àti Tigrai kòkàárí tí Ethiopia àti konsoid, èdè abínibí lo sọ wọn pọ̣̀ ni Gusu ìwọ̀ Òòrùn. Ṣùgbọ́n eyi ti wọn ń ṣọ ni Kanso (200)

(iii) Àwọn ọmọ Tana wọn jẹ mo ìlà Òòrùn àti ìwọ̀ Òòrùn ti ìpààlà wa láàrìn wọn. Àwọn ará tẹ́lẹ̀ kún fún Àríwá ni Kenyan Rendille (32) Boni(5) Lapapọ iye ti àwọn Somali jẹ (8,335) Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ní Somalia, Djiboute, Ila Òòrùn Ethiopia, ati Aríwá ìlà Òòrùn Kẹnya. Ti ìwọ̀ Òòrùn pín tó ṣí ní Daasenech (30) Arbore (1,000-500) àti bóyá èdè Elmọlo. Èkọ́ nípa ìmọ̀ ayé tí ó da wà ní Bayso (500) òhun ní wọ́n ń ṣọ ní agbègbè Abàjà adágún nínú Ethopian Rift Valley tí ó pin ẹya kan pẹlu ìlà Òòrùn atí ìwọ̀ Òòrùn.

(4) Dually dúró fún gẹ́gẹ́ bi okùn ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ní àgbègbè Wayto Valley ṣí ìwọ̀ òòrùn ti Konsout (of 4(n) soke) èyí to yàtọ̀ l’orisiirisi ni Gusu Tsmay (7) pípàdé ẹgbẹ́ onihun ìsùpọ̀ lójúpọ̀ parapọ̀ ní Ethnologue gẹ́gẹ́ bi Gwwada (65-76).

(5) Èdè Cushitic ni Ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ń sọ ni Tanzania, níbi ti wọn ti dúró fún iraqw gẹ́gẹ́ bí ìsùpọ̀ fún apẹẹrẹ (365), Gorowa (30) Burunge (31) Mbugu/Mana (32) ní wọn ṣábà maa ń lò gẹ́gẹ́ bi ojúlówó àpẹ̀ẹrẹ èdè àmúlùmálà àti alaisi Asax àti fún kw’adza ọmọ ẹgbẹ ti i ki i ṣe ọmọ ìlú Tan zania tó jẹ dahalo (3,000) ó sọ̀rọ̀ ní ìletò to ṣúnmọ́ ẹnu ìlú odò Tana ní Kenya.