Jump to content

Kwada Joseph Ayuba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kwada Joseph Ayuba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń sìn gẹ́gẹ́ bí aṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Michika ní ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlè Adamawa báyìí. [1] [2]