Lagos Islanders
Ìrísí
Lagos islanders jẹ ẹgbẹ basketball ní Naijiria ti wón kalè sí ìpínlè Eko, ti a da ni ọdun 1984. Olorin Sound Sultan wà lara àwon to ni egbé Lagos Islanders lati ọdun 2014. Wọn Ma ún gbá ere boolu won pápá Idaraya Rowe Park ni agbegbe Yaba .
Ni odun 2016, wón kopa ninú ìdíje African Basketball League nitori Nigerian Basketball Federation(NBBF) ko dá won mo nigba náà, won fin òfin de won láti mó kopa nínú ìdíje abele[1] sùgbón a fagi lé ofin náà ní odun 2019.[2].
Awọn èye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Premier League Naijiria
- Awọn Nick jáwé olúborí ní (5): 1997, 1998, 1999, 2000, 2001
FIBA Africa Club Championship Cup
- Won gbe ipò kẹta ni odun: 2000
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Dstv Basketball: NBBF bans Warriors, Islanders, Union Bank". Vanguard News. March 14, 2016. Retrieved September 12, 2022.
- ↑ Alao, Seyi (June 21, 2019). "NBBF Premier League commences on July 8". Latest Sports News In Nigeria. Retrieved September 12, 2022.