Lake Ahémé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lake Ahémé
Location Gúúsù ìwọ̀ oòrùn Benin
Coordinates 6°29′42″N 1°58′30″E / 6.495°N 1.975°E / 6.495; 1.975Coordinates: 6°29′42″N 1°58′30″E / 6.495°N 1.975°E / 6.495; 1.975
Primary inflows Couffo River
Primary outflows Aho Channel
Basin countries Benin
Max. length 24 km (15 mi)[1]
Max. width 5.5 km (3.4 mi)[1]
Surface area 78–100 km2 (30–39 sq mi)[2]
Surface elevation 3–5 m (9.8–16.4 ft)[1]
Settlements Agatogbo, Agbanto, Akodéha, Bopa, Dekanmè, Kpomassè, Possotomè, Tokpa-Domè

Lake Ahémé jẹ́ adágún odò kejì tí ó tóbi jùlọ ní Benin, ibi tí ó gbà tó 78 square kilometres (30 sq mi) ní ìgbà ẹ̀rùn, ó sì ma ń tó 100 square kilometres (39 sq mi) nígbà òjò.[2] Gígùn adágún odò náà tó 24 kilometres (15 mi) fífẹ̀ rẹ̀ sì tó 3.6 kilometres (2.2 mi).[1] Odò Couffo ṣàn sínú àríwá ìwọ̀ oòrùn náà.[2]

Ẹ̀yà Pedah àti Ayizo ni àwọn ẹ̀yà méjì gbòógì tí ó ń gbé tí etí groups adágún Ahémé.[2][3] Iṣẹ́ apẹja àti àgbẹ̀ ni iṣẹ́ tí wọ́n ṣe ní agbẹ̀gbẹ̀ náà.[1][2] Àwọn oríṣi ẹja tí ó wà ní adágún Ahémé tó ọ̀kànlẹ́làádọ́rin.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 Hughes, R. H.; Hughes, J. S. (1992). A directory of African wetlands. IUCN. ISBN 2-88032-949-3. https://books.google.com/books?id=VLjafeXa3gMC&pg=PA305. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 Dangbégnon, Constant (2000). Governing Local Commons: What Can be Learned from the Failures of Lake Aheme's Institutions in Benin?. Eighth Biennial Conference of the International Association for the Study of Common Property. Bloomington, Indiana. 
  3. Houngnikpo, Mathurin C.; Decalo, Samuel (2013). Historical Dictionary of Benin. Rowman & Littlefield. ISBN 978-0810871717. https://books.google.com/books?id=0yGPTsRubWEC. Retrieved 28 July 2016. 
  4. "Basse Vallée du Couffo, Lagune Côtiere, Chenal Aho, Lac Ahémé". Retrieved 28 July 2016. 
  5. "Présentation". Archived from the original on 18 August 2016. Retrieved 28 July 2016.