Lamide Akintobi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Lamide Akintobi
Lamide Akintobi portrait.jpg
Lamide Akintobi
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́journalist, television personality
Ìgbà iṣẹ́2006-present

Lamidi Akintobi jẹ́ oníróyìn àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni Nàìjíríà. Ó sì ṣe gẹ́gẹ́ bíi atọkun ìròyìn lórí Channels TV.[1] Ó ti si ṣé pelu Zainab Balogun àti Ebuka Obi-Uchendu gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò The Spot lórí Ebonylife TV.

Ìbéèrè pẹpẹ aiyé àti ẹ̀kọ́ rẹ.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akintobi jẹ́ ọmọ Abẹ́òkúta ni ìpínlè Ogun.[2] Ó gboyè B. A nínú ìmò agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati èdè Spanish láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Volunteer State Community College ni Tennesse àti Texas A&M University - Commerce.[3] Ó gboyè master's rẹ nínú International journalism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí City University ni London.[4] Lamide di ọmọ ẹgbẹ́ Delta Sigma Theta ni ọdún 2004.[5]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akintobi ṣi ṣé gẹ́gẹ́ bíi atọkun ètò ìròyìn lórí Channels TV.[1] Ó si ṣé pelu Zainab Balogun àti Ebuka Obi-Uchendu gẹ́gẹ́ bíi atọkun fún ètò The Spot lórí Ebonylife TV, ó sì gbé ère El Now jáde.[6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]