Langston Hughes
Ìrísí
Langston Hughes | |
---|---|
Fọ́tò Hughes látọwọ́ Carl Van Vechten ní 1936 | |
Ọjọ́ ìbí | James Mercer Langston Hughes Oṣù Kejì 1, 1902 Joplin, Missouri, United States |
Ọjọ́ aláìsí | May 22, 1967 New York City, New York, United States | (ọmọ ọdún 65)
Iṣẹ́ | Poet, columnist, dramatist, essayist, novelist |
Ìgbà | 1926–64 |
James Mercer Langston Hughes (February 1, 1902 – May 22, 1967) je akoewi, aseiwe-aroso, akoere-oritage ati alaroko. O je eni akoko to soro nipa iseona tuntun to un je jazz poetry. Hughes gbajumo fun awon iwe re to ko nigba Harlem Renaissance. O so nigbana pe "Harlem gbajumo".
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |