Jump to content

Lanre Buraimoh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Lanre buraimoh)
Lanre Buraimoh
Ọjọ́ìbí1976[1]
Osogbo, Osun State, Nigeria[2]
Iṣẹ́Artist
Ìgbà iṣẹ́1990–present

Lanre Buraimoh kẹ́kọ̀ọ́ iṣẹ́-onà (ìlẹ̀kẹ̀-híhun) lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ̀, Olóyè Jimoh Buraimoh àti Àlàkẹ́ Buraimoh, tí wọ́n jẹ́ gbajúgbajà onílẹ̀kẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti òkè òkun.[3] Ẹ̀ṣọ̀ òun àrà tí àwọn ẹ̀yà Yorùbá ilẹ̀ adúnláwọ̀ ń fi ìlàkẹ̀ ìbílẹ̀ dá sí adé, bàtà, àti ọ̀pá ìtìlẹ̀ àwọn ọba aládé, ni ó ṣokùnfà ìfẹ́ tí Lanre Buraimoh ní sí iṣẹ́ ìlẹ̀kẹ̀ híhun. Ọgbọ́n àtinúdá alárà titun onílẹ̀kẹ̀ kíkùn ti Buraimoh fi kún ìlẹ̀kẹ̀ ìbílẹ̀ mú kí ẹwà ìlẹ̀kẹ̀ àwọn Yorùbá yọ síi. Ìṣelẹ́ṣọ̀ọ́ yìí sì ṣàfihàn àwọn ìgbàgbọ́ Yorùba nípa ìfẹ́, ìdánilárayá àti ìṣọ̀kan.

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • 2019, Houston Artadia Fellowship[4]
  • 2017, Juror's Award at the University Museum at Texas Southern University

Àwọn ìṣàfihàn rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • 2019, 19th Annual Citywide Exhibition, University Museum at Texas Southern University, Houston, Texas
  • 2019, Summer Group Art Show, Wasagaming Art Center, Manitoba, Canada
  • 2017, Art of Africa, Mytrunk Gallery, Denmark
  • 2012, 12th Annual Citywide Exhibition, University Museum at Texas Southern University, Houston, Texas[5]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Full name & date of birth – 1st paragraph". Ayaka. Archived from the original on 8 October 2013. Retrieved 4 December 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "My encounter with bead painting – Lanre Buraimoh", http://www.vanguardngr.com/2013/06/my-encounter-with-bead-painting-lanre-buraimoh/
  3. "Lanre Buraimoh | Bisong Art Gallery | Houston, TX" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-05-11. Retrieved 2019-05-11. 
  4. "Houston Fellowship". Artadia. 8 October 2018. Retrieved 2019-05-11. 
  5. "MFAH 16TH ANNUAL CITYWIDE AFRICAN AMERICAN ARTISTS EXHIBITION | FreshArts.org". www.fresharts.org. Archived from the original on 2019-05-11. Retrieved 2019-05-11.