Jump to content

Lara George

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lara George
Lara George in 2014
Lara George in 2014
Background information
Ìbẹ̀rẹ̀Lagos State, Nigeria
Irú orinGospel
Occupation(s)Singer/songwriter
Years active1997 - present
LabelsSoforte Entertainment
Associated actsMidnight Crew, Pat Uwaje-King, Lord of Ajasa, Kush

Lara George( tí a bí ní 25th of June, 1978[1]) jé olorin ihinrere omo bíbí ìlú Nàìjirià, sùgbón tí ó ún gbé ní ìlú Amerika

A bí Lara George ní June 25, 1978 sí idile Oluwole Bajomo ni Ipinle Lagos, ipin iṣakoso ti Nigeria.[2]

Ó kàwé ni ilé-ìwé Queen's College ni Èkó tí ó tó di pé ó kàwé ní yunifásitì ìlú Èkó, ìbí tí ó tí gba Master degree ní iyaworan ilé(Architecture).

Lara bèrè orin kíko nígba tí ó wà ní yunifásitì ìlú Èkó, níbi tí o ti darapo mó àwon akorin apejopo ara. [3] Ówà lára àwon egbe akorin(tí a padà tua) tí à ún pè ní "Kush", ara àwon orin tí Lara kókó gbé jáde ni Ìjoba Orun(ní odun 2008), orin náà gbajugbaja nile loko, ósì mú òpòlopò ami eye wa fún.

  1. "Lara George Dazzles In New Birthday Photos - @Larageorge". Praiseworld Radio. 2017-06-23. Retrieved 2022-04-01.  Text " Africa's #1 Online Gospel Radio Station " ignored (help); Text " Nigeria " ignored (help)
  2. "Happy Birthday Lara George! See the Gospel Artist’s New Photos". BellaNaija. 2017-06-23. Retrieved 2022-04-04. 
  3. "I put off having a baby for six years because of my career- Lara George". Vanguard News. 2014-11-29. Retrieved 2022-04-04.