Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Large Hadron Collider)
Jump to navigation Jump to search

Àwọn Akóìjánupọ̀: 46°14′N 06°03′E / 46.233°N 6.05°E / 46.233; 6.05

Nínú ọ̀dẹ̀dẹ̀ ẹ̀rọ ìmúsáré
Large Hadron Collider
(LHC)
LHC.svg
LHC experiments
ATLAS A Toroidal LHC Apparatus
CMS Compact Muon Solenoid
LHCb LHC-beauty
ALICE A Large Ion Collider Experiment
TOTEM Total Cross Section, Elastic Scattering and Diffraction Dissociation
LHCf LHC-forward
MoEDAL Monopole and Exotics Detector At the LHC
LHC preaccelerators
p and Pb Linear accelerators for protons (Linac 2) and Lead (Linac 3)
(not marked) Proton Synchrotron Booster
PS Proton Synchrotron
SPS Super Proton Synchrotron

Àdàkọ:Hadron colliders

Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà tabi Large Hadron Collider (LHC) ni ero imusare eruku pelu okun totobijulo ati togajulo lagbaye. Ó jẹ́ kíkọ́sókè látọwọ́ CERN láti ọdún 1998 dé 2008, pẹ̀lú èrò láti gba àwọn aṣefísíksì láyè láti ṣe àdánwò ìsọtẹ́lẹ̀ àwọn orísi àròjinlẹ̀ físíksì eruku àti físíksì olókun-gíga, àti àgàgà láti wá bọ́yá bósónì Higgs wà lóòótọ́[1] àti orísirísi àwọn eruku tuntunàjọbáramu adárajùlọ ṣe àsọtẹ́lẹ̀.[2] Ìrètí ni pé LHC yíò wá ìdáhùn is expected to address some of the ọ̀pọ̀ àwọn ìbérè inú físíksì, nípa èyí láti mú ìlọsíwájú bá òye àwọn òfin àdánidá jínjnlẹ̀. Ó ní ẹ̀rọ ìwárí mẹ́fà tí ìkọ̀ọ̀kan wà fún ìwàdìí ohun pàtó kan.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Missing Higgs". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10. 
  2. "Towards a superforce". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10.