Jump to content

Ónjẹ Alẹ́ Olúwa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Last Supper)
The Last Supper (Convent of Sta. Maria delle Grazie, Milan, Italy (1498), by Leonardo da Vinci).

Ninu Ihinrere esin Kristi Onje Ale Oluwa ni onje igbeyin ti Jesus pin pelu awon Aposteli Mejila ti won je omo eyin re ki o to je kikan mo agbelebu.