Laura Chinchilla

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Laura Chinchilla
Chinchilla Adelante.jpg
Aare ile Kosta Rika
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
8 Osu Karun 2010
Vice PresidentÀkọ́kọ́: Alfio Piva
Ìkejì: Luis Liberman
AsíwájúÓscar Arias
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹta 1959 (1959-03-28) (ọmọ ọdún 64)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Liberation Party
Alma materUniversity of Costa Rica
Georgetown University
{{{blank1}}}José María Rico

Laura Chinchilla Miranda (ojoibi 28 March 1959) je oloselu ara Kosta Rika ati obinrin akoko Aare ile Kosta Rika. Ohun ni ikan ninu awon Igbakeji Aare si Óscar Arias Sánchez ati Alakoso Idajo ijoba re.[1] Ohun aduroibo fun egbe PLN fun idiboyan Aare ninu ibiboyan gbogbogbo odun 2010 nibi to ti bori pelu 46.76% awon ibo didi.[2] O je obinrin kefa ti yio je didiboyan bi Aare ni orile-ede Amerika Latini kan.[3] She was sworn as president of Costa Rica on May 8, 2010.[4]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Chiefs of State and Cabinet members of Foreign Governments". The Central Intelligence Agency of America. Retrieved 22 February 2010. 
  2. "2010 Presidential election results, (in Spanish)". Supreme Court of Elections. 8 February 2010. Retrieved 22 February 2010. 
  3. "Costa Rica to inaugurate first female president Saturday". Tribunal Supremo de Elecciones, República de Costa Rica. 2010-05-06. Retrieved 2010-05-08. 
  4. Economist.com