Lauryn Hill
Ìrísí
Lauryn Hill | |
---|---|
Hill performing in 2014 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Lauryn Noelle Hill |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi |
|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kàrún 1975 Newark, New Jersey, U.S. |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 1988–present |
Labels | |
Associated acts | |
Website | lauryn-hill.com |
Lauryn Noelle Hill (ọjọ́ìbí May 26, 1975) ni akọrin, akọ̀wé-orin, àti olórin rap ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ ìkan nínú ọmọ ẹgbẹ́ olórin rap Fugees, àti fún àwo-orin tó dá gbé jáse tó ún jẹ́ The Miseducation of Lauryn Hill, tó gba ẹ̀bùn ọ̀pọ̀lọpọ̀, tó sì léwájú ọ̀pọ̀ rẹ́kọ́rdù ìtajà àwo-orin. Hill ni ìkan nínú àwọn olórin rap tó lókìkí jùlọ, àti ìkan láàrin àwọn aléwájú orin Neo soul.