Jump to content

Òfin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Law)
Iya 'Dajo ni ami-idamo fun onidajo.[1][2] Idajo je fifihan bi osa to ni awon ami-idamo meta fun ona to bofin mu: ida ton duro fun agbara igbero ile-ejo; iwon to duro fun gbigba gbogbo ejo ro; ati iboju to duro fun aifi si egbe kankan.[3]

Òfin[4] je sistemu awon ilana kan, to se gbe ro nipa ikojopo awon ifidimule kan.[5] O un tona iselu, ekonomiki ati awujo lorisirisi ona, o si je olulaja akoko lawujo fun ibasepo larin awon eniyan. Ofin adehun un setona ohun gbogbo latori rira tiketi oko de idunadura ni ile pasiparo. Ofin Ohun ini n setoka awon eto ati ojuse to jemo fifun ati nini ohun ini araeni (ti a n pe ni ẹrù) ati ohun ini gidi (bi ile ti ko se mu kuro). Ofin igbalawin je mo dukiya ti a fi pamo fun idaabo inawolori ati oninawo, nigbati ofin ibaje gbani laaye lati gba esan atunse ti eto tabi ohun ini eniyan ba bibaje lowo elomiran. Ti ibaje yi ba je sisododaran ninu iwe ofin, ofin odaran ni yio so bi ijoba yio se fi esun kan iru eni be. Ofin ibagbepapo un pese ona dida ofin, idaabo bo awon eto omoniyan ati idiboyan awon asoju oloselu. Ofin amojuto lo n sagbeyewo awon ipinu awon ile-ise ijoba, nigbati ofin akariaye un dari ìṣe larin awon orile-ede lati tona idunadura, ayika tabi imuse ologun. Ninu iwe to ko ni 350 kJ, Aristotle amoye ara Griisi so pe, "Ona to bofin mu dara ju ona enikeni lo."[6]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Hamilton, Marci. God vs. the Gavel, page 296 (Cambridge University Press 2005): “The symbol of the judicial system, seen in courtrooms throughout the United States, is blindfolded Lady Justice.”
  2. Fabri, Marco. The challenge of change for judicial systems, page 137 (IOS Press 2000): “the judicial system is intended to be apolitical, its symbol being that of a blindfolded Lady Justice holding balanced scales.”
  3. Luban, Law's Blindfold, 23
  4. From Old English lagu "Words of Mel"; legal comes from Latin legalis, from lex "law", "statute" (Law, Online Etymology Dictionary; Legal, Merriam-Webster's Online Dictionary)
  5. Robertson, Crimes against humanity, 90; see "analytical jurisprudence" for extensive debate on what law is; in The Concept of Law Hart argued law is a "system of rules" (Campbell, The Contribution of Legal Studies, 184); Austin said law was "the command of a sovereign, backed by the threat of a sanction" (Bix, John Austin); Dworkin describes law as an "interpretive concept" to achieve justice (Dworkin, Law's Empire, 410); and Raz argues law is an "authority" to mediate people's interests (Raz, The Authority of Law, 3–36).
  6. n.b. this translation reads, "it is more proper that law should govern than any one of the citizens: upon the same principle, if it is advantageous to place the supreme power in some particular persons, they should be appointed to be only guardians, and the servants of the laws." (Aristotle, Politics 3.16).