Lebogang Phalula
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kẹẹ̀sán osù kejìlá Ọdún 1983 (Ọdún Méjìdínlógójì) |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Erẹ́ìdárayá | Eré sísá ọ̀nà jíjìn |
Lebogang Phalula tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀san Oṣù kejìlá ọdún 1983 jẹ́ olùsáré ọlọ́nàjínjìn fún orílẹ̀ ède South Africa kan .
Ní ọdún 2009, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà fún IAAF World Cross Country Championships ti 2009 tí ó wáyé ní Amman, Jordani. O pari pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gbọ̀n. [1]
Ní ọdún 2009, ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin àgbà fún IAAF World Cross Country Championships ti 2009 tí ó wáyé ní Amman, Jordani. O pari pẹ̀lú ipò kọkàndínlọ́gbọ̀n. [1]
Ní ọdún 2011, o gba ìdádúró oṣù mẹ́fà ní bí eré ìdárayá léyìn tí wọ́n rí wípé àyẹwò fi hàn wípé o ní methylhexaneamine ti a fi òfin dé.
O jáwé Olúborí fún eré ọgọ́ọ̀rún mẹ́jọ mítaà tí a sọ àkọ́lé rẹ̀ níbi 2005 South African athletics championships . [2]
ó ní ọmọ ìyá bìnrin tí ó jẹ́ Ìbejì rẹ̀ tí òhun náà jẹ́ eléré ìdárayá tí à n pè ní Dina Lebo Phalula . [3]
- Àkójọ ìṣẹ̀lẹ̀ tí kò hàn gbangbanínú àwọn eré ìdárayá
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedsenior_women_race_iaaf_world_cross_country_championships_2009
- ↑ South Africa championships, Durban 15-17/04. Africa Athle. Retrieved 2021-01-23.
- ↑ Buthelezi, Mbongiseni (2019-09-04). Phalula twins aim for Tokyo via Cape Town. IOL. Retrieved 2021-01-23.
ìjápọ ìta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lebogang Phalula ní World Athletics