Leko Jafaru Gambo
Ìrísí
Leko Jafaru Gambo je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju ti o n sójú àgbègbè Bogoro / Dass/ Tafawa Balewa ti Ìpínlẹ̀ Bauchi ni Ile-igbimọ Asofin kẹwàá. [1] [2] [3] [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://tribuneonlineng.com/reps-member-jafaru-awards-scholarship-to-200-indigent-students/
- ↑ https://independent.ng/christmas-leko-distributes-food-scholarship-worth-n100m/
- ↑ https://nannews.ng/2023/09/15/appeal-court-upholds-election-of-bauchi-rep-member-jafaru-leko/
- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2023/06/26/dogaras-successor-leko-promises-all-inclusive-representation/