Leon Balogun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Leon Aderemi Balogun (tí wón bí ní 28 June 1988) je agbaboolu-elese omo orilede Naijiria ti a bi si orilede Jẹ́mánì[1]. O je adi eyin mu fun egbe agbabolu Rangers. Balogun ti gba boolu fun iko agbaboolu Türkiyemspor Berlin, Hannover 96, Werder Bremen, Fortuna Düsseldorf, Darmstadt 98, Mainz 05, Brighton & Hove Albion, Wigan Athletic, a ti Queens Park Rangers seyin.

Egbe Agbaboolu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Balogun ko pa takun-takun fun ìgbà àkókó ninu egbe idije Bundesliga ni ojo Kokandinlogun Osu Igbe Odun 2019 (19 April 2009) ninu egbe agbaboolu Hannover 96 nibi ti won ti pade egbe agbaboolu Hamburger SV[2].

Leyin ti adehun re pelu egbe agbaboolu Fortuna Düsseldorf pari ni igba ooru (summer) odun 2014, o wa lai ni egbe agbaboolu kankan fun osu meeta leyin naa lo wa darapo mon egbe agbabolu Darmstadt 98. O t'owo b'owe adehun pelu egbe agbaboolu naa titi di opin saa boolu 2014-15[3].

  1. https://goalballlive.com/leon-balogun-profile/
  2. "Petric als Blitzarbeiter" (in Èdè Jámánì). kicker.de. Archived from the original on 11 June 2009. Retrieved 3 April 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Lilien verstärken sich mit Leon Balogun" [Lilien strengthens with Leon Balogun] (in Èdè Jámánì). SV Darmstadt 98. 2 October 2014. Archived from the original on 4 October 2014. Retrieved 12 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)