Leonard Auala
Ìrísí
Àdàkọ:Pre-nominal styles Leonard Auala | |
---|---|
Bishop | |
1967 | |
Church | Evangelical Lutheran Church in Namibia |
Personal details | |
Born | 25 September 1908 Iiyale, Oniipa, Ovamboland, German South West Africa[2] |
Died | 4 December, 1983 Onandjokwe Lutheran Hospital,[1] South West Africa |
Leonard Nangolo Auala (tí a bí ní ọjọ́ kàrùnlélógun oṣù Kẹ̀sán án ọdún 1908 ní Iiyale, Oniipa, Ovamboland, German South West Africa tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kejìlá ọdún 1983 ní Onandjokwe, South West Africa[3]) jẹ́ adarí ìjọ Lutheran nígbà ayé rẹ̀.
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Auala ní Oniipa, Ovamboland, German South West Africa. A bi sí inú ìdílé Nakanyala Vilho yaAwala (Shihwa) waAmukwiyu àti Nekwaya Loide yaShikongo shaNangolo dhaAmutenya.[3]
Ó lọ ilé ìwé prámárì ní Oniipa láàrin ọdún 1919 sí 1929, a sì kọ nípa ìmọ̀ iṣé àlùfáà láàrin ọdún 1929 àti 1931. Ní 1934 sí 1935, o kàwé ní Augustineum, Okahandja, ó sì tún kọ́ nípa iṣẹ́ àlùfáà ní Elim ní ọdún 1942, Ní ibi tí a ti yán gẹ́gẹ́ bi àlùfáà.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ihamäki, Kirsti (1985). Leonard Auala: Mustan Namibian paimen. Helsinki: Kirjaneliö. pp. 270–271. ISBN 951-600-677-9.
- ↑ Kutsu Helsingin yliopiston teologisen tiedekunnan tohtoripromootioon marraskuun 2. päivänä 1967, p. 32. Helsinki, 1967.
- ↑ 3.0 3.1 Nambala, Shekutaamba V. V. (1995). Ondjokonona yaasita naateolohi muELCIN 1925–1992. Oniipa, Namibia: ELCIN. pp. 58–59.