Jump to content

Léopold Sédar Senghor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Leopold Sedar Senghor)
Léopold Sédar Senghor
Àarẹ ilẹ̀ Senegal
In office
6 September 1960 – 31 December 1980
AsíwájúIjoba Alamusin ile Faranse
Arọ́pòAbdou Diouf
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1906-10-09)Oṣù Kẹ̀wá 9, 1906
Joal, Senegal
AláìsíDecember 20, 2001(2001-12-20) (ọmọ ọdún 95)
Normandy, France
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSenegalese Democratic Bloc

Léopold Sédar Senghor (9 October 1906  – 20 December 2001) je akoewi, oloselu ati ajiro asa omo ile Senegal to gori ipo gege bi Aare akoko orile-ede Senegal lati 1960 de 1980. O je ikan pataki lara awon onimo ijinle ni ile Afrika.