Leslie Schofield

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Leslie Schofield
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kejìlá 1938 (1938-12-12) (ọmọ ọdún 85)
Oldham, Lancashire, England
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1968–2006

Leslie Schofield (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejìlá ọdún 1938) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain tí ó gbajúmọ̀ ní United Kingdom fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Jeff Healy nínú soap opera EastEnders, ó kó ipa yìí láàrin ọdún 1997 sí 2000.[1] Ó farahàn nínú EastEnders gẹ́gẹ́ bi Brain Wicks ní ọdún 1988 àti 1989.

Schofield kó ipa Chief Bast nínú eré Star Wars Episode IV: A New Hope ní ọdún 1977. Ó tún farahàn nínú Star Wars Holiday Special. Àwọn eré míràn tí ó ti farahàn ni The Body Stealers (1969), Twinky (1969), Villain (1971), The Ruling Class (1972), The Glitterball (1977), The Wild Geese (1978), Force 10 from Navarone (1978), Silver Dream Racer (1980), Dead Man's Folly (1986), Doctor Who, The War Games (1969) The Face of Evil (197àti, bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àwọn Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Telegraph, Grimsby (2013-07-01). "Thousands raised at annual charity golf day". Grimsby Telegraph. Archived from the original on 2015-09-24. Retrieved 2016-12-19.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)