Jump to content

Libianca

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use mdy dates

Libianca
Orúkọ àbísọLibianca Kenzonkinboum Fonji
Ọjọ́ìbíBamenda, Cameroon
Ìbẹ̀rẹ̀Minnesota, U.S.
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • audio engineer
Years active2019–present
Labels

Libianca Kenzonkinboum Fonji,tí wọ́n mọ̀ sí Libianca, jẹ́ ọ̀kọrin Afrobeat ti won bí sí Kameroon tí ó sì ń kọrin ní ìlú Amẹ́ríkà.[1] Ó wà lára àwọn tí wọn díje lórí ètò tí wón ń pè ní The Voice èyí tí o jẹ́ Ìràn kàn ní ìlú Amẹ́ríkà ní ọdún 2021.[2] Ó ti ìpasẹ̀ orin àkọ́kọ́ tí tí ó pè ní "People" tí ó fí di olókìkí ní ọdún 2022, èyí tí ó jẹ́ pé Cyclothymia ní ó wù lórí. Orin "People" jẹ́ orin tí òkiki rẹ kàn dé bi ó wà ní nípò Kejì lórí Billboard kan ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tí wón ń pè ní U.S Billboard Magazine tí ó jẹ́ tí àwọn orin Afrobeat beats tí ó sì jẹ́ ohun tí ó tán ká lórí èrò Social Media.[3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Ìgbé Ayé àti Iṣẹ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí sí Minneapolis ní Ìlú tí wọ́n pè ní Minnesota, sùgbọ́n Libianca wà láti orílè èdè Kamẹrúùn.[4]  Ó díje nínú 21st season tí NBC tí wọn pè ní "The Voice ", níbi tí Blake Shelton tí jẹ́ Olùkọ́ni rẹ̀.[5][6] She made her way to the top 20 before being eliminated.[7] Ó jẹ́ ọ̀kọrin ní ilé-iṣẹ́ orin tí wọn pè ní 5k Records and RCA Records.[8]

'Àdákọ

List of singles
Title Year Peak chart positions Certifications Notes
AUS
[9]
CAN
[10]
FRA
[11]
NLD
[12]
NZ
[13]
SWE
[14]
SWI
[12]
UK
[15]
US
Bub.

[16]
WW
[17]
"People" 2022 60 57 68 30 6 16 29 13 3 69

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Conteh, Mankaprr (January 20, 2023). "Libianca Is the Afro Soul Siren Who Can Do Everything" (in en-US). Rolling Stone. https://www.rollingstone.com/music/music-features/libianca-interview-new-single-people-1234664675/. Retrieved 2023-01-26. 
  2. "LIBIANCA: The Voice contestant - NBC.com". NBC (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-07. 
  3. Rys, Heran Mamo,Dan; Mamo, Heran; Rys, Dan (January 24, 2023). "Afrobeats Fresh Picks of the Month: Burna Boy, Libianca, Aya Nakamura & More" (in en-US). Billboard. https://www.billboard.com/music/music-news/best-new-afrobeats-songs-burna-boy-libianca-aya-nakamura-fresh-picks-1235203930/. Retrieved 2023-01-26. 
  4. Ihejirika, Uzoma (January 23, 2023). "Best New Music: Libianca's "People (Check On Me)" Gets Real About Mental Health". The NATIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-26. 
  5. Henderson, Cydney. "'The Voice': Blake Shelton 'heartbroken' after eliminating his own 'God's Country' singer". USA TODAY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-26. 
  6. Donnellan, Sara (October 7, 2021). "WATCH: 'The Voice' Contestant Picks Coach Based on a Sign from God". Heavy.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on January 26, 2023. Retrieved 2023-01-26. 
  7. Tribune, Neal Justin Star. "Minnesota contestant Libianca eliminated from 'The Voice'". Star Tribune. Retrieved 2023-01-26. 
  8. "Rising Star Libianca Shares Visuals To Hit 'People' – OkayAfrica". www.okayafrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-26. 
  9. "The ARIA Report: Week Commencing 6 February 2023". The ARIA Report (Australian Recording Industry Association) (1718): 4. February 6, 2023. 
  10. "Billboard Canadian Hot 100: Week of February 4, 2023". Billboard. https://www.billboard.com/charts/canadian-hot-100/2023-02-04/. Retrieved January 31, 2023. 
  11. "Top Singles (Week 8, 2023)" (in French). SNEP. Retrieved February 27, 2023. 
  12. 12.0 12.1 "Libianca – People". dutchcharts.nl (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). Retrieved January 28, 2023. 
  13. "NZ Top 40 Singles Chart". Recorded Music NZ. February 27, 2023. Archived from the original on February 24, 2023. Retrieved February 25, 2023. 
  14. "Veckolista Singlar, vecka 4". Sverigetopplistan. Retrieved January 28, 2023. 
  15. "Libianca | full Official Chart History". Official Charts Company. Retrieved February 24, 2023. 
  16. "Bubbling Under Hot 100: Week of February 4, 2023". Billboard. https://www.billboard.com/charts/bubbling-under-hot-100-singles/2023-02-04/. Retrieved January 31, 2023. 
  17. "Billboard Global 200: Week of February 4, 2023". Billboard. https://www.billboard.com/charts/billboard-global-200/2023-02-04/. Retrieved January 31, 2023. 
  18. Àdàkọ:Cite certification
  19. Cusson, Michael (March 29, 2022). "Billboard U.S. Afrobeats Songs" (in en-US). Billboard. https://www.billboard.com/charts/billboard-u-s-afrobeats-songs/. Retrieved 2023-01-26. 
  20. "Official Afrobeats Chart Top 20 | Official Charts Company". www.officialcharts.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-26. 

Àdàkọ:The Voice (U.S.)