Lilian Adera
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Lilian Odaa Adera | ||
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kàrún 1994 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kisumu, Kenya | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Vihiga Queens | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Lilian Adera jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7, may ni ọdun 1994. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ kenya[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lilian kopa ninu Nation Cup awọn obinrin ilẹ afirica[4].