Lillian Echelon Mbadiwe
Ìrísí
Lillian Echelon Mbadiwe | |
---|---|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Film actress, model, Producer, Business Woman |
Lillian Echelon Mbadiwe jẹ́ òṣèrébìnrin, àti oníṣòwò tó gbajúgbajà nínú iṣẹ́ fíìmù ṣíṣé látàri fíìmù rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Black rose.[1]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Break The Silence
- Breaking Chain
- Black Rose[2]
- Lily’s New Friend
- Living Nightmares
- Seminarian In Love
- Laurie
- Love Unusual
- The Debt
- Flipside
- Yahoo+[3]
Àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní AMVCA, ti ọdún 2018.[2]
Àmì-ẹ̀yẹ Golden Discovery Actor ní Gold Movie Award[4]
Àmì-ẹ̀yẹ Golden Actress fún dírámà ní Gold Movie Award Africa.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Online, Tribune (2020-08-26). "Success in Nollywood is not easy —Lilian Echelon Mbadiwe". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ 2.0 2.1 "AMVCA 2018 : Adekola Odunlade, Omotola Ekeinde win best actor, actress". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-01. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Nwogu, Precious 'Mamazeus' (2022-06-22). "Yahoo+ confirmed for July theatrical debut". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ Ayamga, Emmanuel (2018-06-04). "Dumelo, McBrown and the full list of winners at 2018 Golden Movie Awards". Pulse Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ "Winners at the Golden Movie Awards Africa 2018 – Glitz Africa Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.