Linda Eshun
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kẹjọ 1992 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Sekondi-Takoradi, Ghana | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Hasaacas Ladies F.C. | |||
National team‡ | |||
2014– | Ghana women's national football team | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Linda Eshun jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kaarun, óṣu August ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Hasaacas gẹgẹbi defender[1].
Aṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Linda kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].