Jump to content

Linda Osifo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Linda Adesuwa Osifo
in 2019
Ìbí1991 July 27
Benin, Edo State, Nigeria
Iṣẹ́Actress, TV Host

Linda Osifo (bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1991)jẹ́ òṣèré àti atọkun ètò lórí tẹlẹfíṣọ̀nù ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1][2][3][4]. Ó gbé ipò kejì nínú ìdíje Miss Nigeria Entertainment ní ọdún 2011, ó sì gbé ipò kẹta níbi ìdíje Miss AfriCanada ní ọdún 2011. Ní ọdún 2015, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ láti ọ̀dọ̀ ELOY Awards[5] fún ipa tí ó kó nínú eré Desperate Housewives Africa. Òun ní olùdásílẹ̀ LAOFFoundation.

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Linda sí ìlú Benin ní Ìpínlẹ̀ Ẹdó. Òun ní obìnrin àkọ́bí tí àwọn òbí rẹ bí. Ó gboyè nínú ìmò Psychology láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí York University ní ọdún 2013.

Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2012, pẹ̀lú eré Family Secrets, In New Jersey èyí tí Ikechukwu ṣe adarí fún[6]. Lèyín tí ó padà sí ìlú Nàìjíríà ní ọdún 2013, ó farahàn nínú eré King Akubueze.[7] Ó kọ ipa Nínà Fire nínú eré Tinsel. Ní ọdún 2017, ó kó ipa Adesuwa Dakolo nínú eré Fifty[8] àti ipa Noweyhon nínú eré Jemeji[9]. Òun àti Segun Arinze ní atọ́kun fún ètò Give n Take National Jackpot[10]. Ní oṣù kẹfà ọdún 2018, ó wá láàrin àwọn tí ó ṣe ìpolówó fún Campari Make it Red.[11]

Ọdún Ẹ̀bùn Category Èsì
2016 Diaspora Entertainment Awards Best Actress Nominated
2015 African Entertainment Awards Canada Best Actor Won[12]
2015 Exquisite Ladies of the Year Award Best Actress in a series Nominated
2018 Starzz Award Creative Actor of the Year Won

Àwọn Ìtọ́kàsi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "BN Style Focus: Linda Osifo's 9 Most Stylish Moments wearing Nigerian Designs on #GntJackpot Show - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-04-25. 
  2. "7 Things You Probably Didn’t Know About Actress, Linda Osifo" (in en-US). Nigerian Celebrity News + Latest Entertainment News. 2017-10-30. Archived from the original on 2021-05-22. https://web.archive.org/web/20210522084814/https://stargist.com/cover/linda-osifo-biography-wikipedia-profile/. 
  3. Izuzu, Chidumga. "Linda Osifo talks career, sexual harassment in Nollywood" (in en-US). Archived from the original on 2018-06-23. https://web.archive.org/web/20180623033326/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/linda-osifo-talks-career-sexual-harassment-in-nollywood-id7693136.html. 
  4. "Being a lady in entertainment is hard –Linda Osifo" (in en-US). Punch Newspapers. http://www.punchng.com/being-a-lady-in-entertainment-is-hard-linda-osifo/. 
  5. "Yemi Alade, Seyi Shay, Cynthia Kamalu, Linda Osifo nominated for ELOY Awards | EbonyLife TV". ebonylifetv.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-06-20. Retrieved 2018-04-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Kanjo, Ernest. "TIPTOPSTARS - ONLINE MAGAZINE Array Series: Family Secrets is next explosion". www.tiptopstars.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-04-26. 
  7. "Clem Ohameze, Michael Godson & Nuella Njubuigbo Star In KING AKUBUEZE - Powered By iROKOtv PLUS - irokotv blog" (in en-US). irokotv blog. 2014-04-04. http://blog.irokotv.com/clem-ohameze-michael-godson-nuella/. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  8. Fifty (TV Series 2017– ), retrieved 2018-04-26 
  9. "Images about #AMJEMEJI tag on instagram". www.pictame.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-04-26. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  10. "GIVE N TAKE NATIONAL LOTTERY JACKPOT WITH SEGUN ARINZE STARTS JUNE 25TH". http://www.cknnigeria.com/2017/06/give-n-take-national-lottery-jackpot.html. 
  11. "2Baba, Harrysong, Tobi, Teddya, Linda Osifo & Others Headlines The Launch of Campari ‘Make it Red’ - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2018-06-21. https://www.vanguardngr.com/2018/06/2baba-harrysong-tobi-teddya-linda-osifo-others-headlines-launch-campari-make-red/. 
  12. "Full List of Nominees at 2017 African Entertainment Awards | 360Nobs.com". www.360nobs.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-04-26. Retrieved 2018-04-25.