Linux
Appearance
Linux (tí wọ́n ń pè báyìí /ˈlɪnəks/) jẹ́ ètò àwọn ọ̀nà iṣé ẹ̀rọ kọ̀mpútà tí ó dàbí Unix tí ó bá POSIX mu tí wọ́n tòpọ̀ lábẹ́ lílo lọ́fẹ́ fún ìdàgbàsókè software.[1][2] Àwọn ẹ̀yà Linux tí a mọ̀ ni Linux Kernel, ètò àwọn ọ̀nà iṣẹ́ kernel tí Linux Torvalds ṣàgbéjáde rẹ̀ ní Ojọ́ karún Oṣù ikẹwá Ọdún 1991. Free Software Foundation lo orúkọ GNU/Linux láti ṣàpèjúwe ètò àwọn ọ̀nà iṣé, tí ó fa rògbòdìyàn.[3]
Àwọn àtúnṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Free On-Line Dictionary of Computing (June 2006). "Linux". Retrieved September 15, 2009.
- ↑ "Conflicts between ISO/IEC 9945 (POSIX) and the Linux Standard Base". opengroup.org. July 29, 2003. Retrieved April 27, 2014.
- ↑ Eckert, Jason W. (2012). Linux+ Guide to Linux Certification (Third ed.). Boston, Massachusetts: Cengage Learning. p. 33. ISBN 978-1111541538. https://books.google.com/books?id=EHLH4S78LmsC&pg=PA33. Retrieved April 14, 2013.