Jump to content

List of Railway lines in China

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àtòjọ àwọn ojú ọ̀nà rélùwéè ní orịlẹ̀-èdè China. rail transport in China. Láti mọ̀ nípa àwọn tí wọ́n yára jùlọ, ẹ wo the high-speed network, ẹ sì lè wo àwọn tí wọ́n ń lo iná mọ̀nà-mọ́ná List of high-speed railway lines in China.

Èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ láti Ẹkùn Àríwá-Gúsù

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
The map of the railway network of China as of February 2020.
The 8 horizontal and 8 vertical mainlines of Chinese railway

Lára àwọn ọkọ̀ ojú-irin akérò ni Jingshan Railway, Shenshan Railway, Changda Railway|Changda Railway, Changchun-Shenyang Portion àti ọkọ̀ ojú-irin Changbin wà tí wọ́n sì ń pè wọ́n ní Jingha Railway (Beijing-Harbin).

Apá Beijing-Shanghai

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Jingshan Railway Beijing-tianjin Portion, Jingpu Railway ati Huning Railway àpapọ̀ wọn ni wọ́n ń pè ní ọkọ̀ ojú-irin akérò Jinghu Railway(京沪线) .

Apá Beijing-Kowloon

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Jingjiu Railway ni ó ń lo ojú-ọ̀nà kan náà pẹ̀lú Guangmeishan Railway làárín Longchuan àti Dongguan. Bákan náà ni ó tún ń lo ojú-ọ̀nà kan náà pẹ̀lú Guangshen Railway láàrín Dongguan àti Shenzhen. Ó sì tún gba ẹnu ibodè East Rail line lọ sí Kowloon, ní ìlú Họ́ng Kọng.

Apá Beijing-Guangzhou

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Apá Datong-Zhanjiang

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹkun Ìwọ̀ Oòrùn-Ìlà Oòrùn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Yangtze River Valley

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ọ̀nà tí wọ́n já pọ̀ mọ́ra wọn lábẹ́lé ni

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ojú ọ̀nà agbègbè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Rélùwéè tí wọ́n lo Èédú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ọ̀nà tí wọ́n já pọ̀ mọ́ ara wọn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ojú ọ̀nà rélùwéè tẹ́lẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn àsopọ̀ ìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àdàkọ:Transport in China