Little Ephraim Robin John àti Ancona Robin John

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Little Ephraim Robin John àti Ancona Robin Robin John jọ jẹ́ àwọn oníṣòwò ẹrú ilẹ̀ Afirika ní sẹ́ńtúrì kejìdínlógún, tí wọ́n padà fún àwọn ẹrúkùnrin tí wọ́n jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ti Old Town Calabur, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní òmìnira ọrundun 18th, ẹrú nigbamii, ati nikẹhin awọn ọkunrin.[1] Ancona ò kì í ṣe ọmọ tàbí ọmọ àbúrò Little Ephraim.

Wọ́n rí àwọn ọmọkùnrin tó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ ìdílé Efik, gẹ́gẹ́ bí i ohun-ìní tó ṣọ̀wọ́n, nítorí wọ́n ń sọ èdè púpọ̀ (pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì), wọ́n mọ̀ ọ́n kọ, wọ́n sì mọ̀ ọ́n kà, wọ́n le ṣe ìtàkurọ̀sọ dáadáa, àti pé wọ́n ní òye kíkún nípa òwò-ẹrú.[2]

Wọ́n kó àwọn ọkùnrin méjì yìí lẹ́rú nígbal tí wọ́n ń kópa nínú ìrìn-àjò òwò-ẹrú kan. Wọ́n tà wọ́n fún àwọn olówò ẹrú ti ilẹ̀ Britain, nígbà tí ọba ti Old Town, ìyẹn Grandy King George ń ṣe ìdúnàdúra ìṣòwò pẹ̀lú Duke ti New Town.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Roark, James L.; Johnson, Michael P.; Cohen, Patricia Cline; Stage, Sarah; Hartmann, Susan M. (2012-03-01) (in en). The American Promise, Volume A: A History of the United States: To 1800. Macmillan Higher Education. pp. 123–124. ISBN 9781457626524. https://books.google.com/books?id=XbEkAAAAQBAJ&q=Ancona+Robin+Robin+John. 
  2. "Ancona Robin John and Little Ephraim Robin John | Slavery and Remembrance". slaveryandremembrance.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-29.