Little Walter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Little Walter
Fáìlì:Little Walter.jpg
Background information
Orúkọ àbísọMarion Walter Jacobs
Ọjọ́ìbí(1930-05-01)Oṣù Kàrún 1, 1930
Marksville, Louisiana, U.S.
Ìbẹ̀rẹ̀Chicago, Illinois
AláìsíFebruary 15, 1968(1968-02-15) (ọmọ ọdún 37)
Chicago, Illinois
Irú orin
Occupation(s)Musician
Instruments
  • Harmonica
  • vocals
  • guitar
Years active1945–1968
Labels
Associated acts
Websitelittlewalterfoundation.org

Marion Walter Jacobs (May 1, 1930 – February 15, 1968), tó gbajúmọ̀ bí i Little Walter, jẹ́ olórin, akọrin, àti akọ̀wé-orin blues. Ó jẹ́ ará ilẹl America tí ó kọrin lọ́nà tuntun bí i Jimi Hendrix.[1] Ìṣọwọ́korin rẹ̀ mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ìrètí ohun tí orin blues máa dà lọ́jọ́ iwájú.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Glover, Tony; Dirks, Scott; and Gaines, Ward (2002). Blues with a Feeling: The Little Walter Story. Routledge Press.
  2. Dahl, Bill Little Walter: Biography. Allmusic.com.