Lokossa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Location of Lokossa in Benin

Lokossa ni oluilu Ipinpa Mono ni orile-ede Benin pelu onibugbe 36,954 (2002). [1] Lokossa tumosi "ni abe igi mangoro".


Coordinates: 6°38′N 1°43′E / 6.633°N 1.717°E / 6.633; 1.717


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]