Lola Eniola-Adefeso

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lola Eniola-Adefeso
Eniola-Adefeso in NIGMS Findings Magazine, 2009
ÌbíMaryland, USA
Ilé-ẹ̀kọ́University of Michigan
Baylor College of Medicine
Ibi ẹ̀kọ́University of Maryland, Baltimore County
University of Pennsylvania

Omolola (Lola) Eniola-Adefeso jẹ́ onímọ̀ chemical engineer àti ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Chemical Engineering, Biomedical Engineering, àti Macromolecular Science àti Engineering ní University of Michigan. Eniola-Adefeso jé ọ̀kan lára àwọ olùdásílẹ̀ àti onímọ̀ sáyéǹsì àgbà ní Asalyxa Bio.[1] She was going to attend medical school but became interested in chemical engineering.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Highways to Healing - Omolola Eniola-Adefeso '99, ChemEng". 2 September 2011. 
  2. "Meyerhoff Scholar – News and Stories for UMBC Alumni". umbcalumni.wordpress.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-05-10. Retrieved 2018-05-09.