Lorna Nyarinda
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Lorna Nyarinda Nyabuto | ||
Ọjọ́ ìbí | 13 Oṣù Kẹ̀wá 2000 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kenya | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Vihiga Queens | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Vihiga Queens | |||
National team | |||
2021– | Kenya women's national football team | 1 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Lorna Nyarinda jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 13, óṣu october ni ọdun 2000. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun Vihiga Queens FC[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lorna ṣe debut fun awọn agbagbọọlu to qualify fun Nation Cup awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2022.[4]
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://nation.africa/kenya/sports/football/harambee-starlets-players-check-in-for-residential-camp-3579252?view=htmlamp
- ↑ https://www.the-star.co.ke/sports/football/2022-01-29-ruthless-vihiga-extinguish-sparks/
- ↑ https://www.goal.com/en-sa/amp/news/2022-awcon-qualifiers-akida-back-in-provisional-harambee/bltc07f12ffa2f4da24
- ↑ https://globalsportsarchive.com/people/soccer/lorna-nyarinda/525330/