Louise Barnes
Ìrísí
Louise Barnes | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Louise Barnes 26 Oṣù Kẹrin 1974 South Africa |
Iṣẹ́ | Actress, voice artist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Louis Barnes (bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ọdún 1974)[1] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó di gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Surviving Evil ni ọdún 2009. Ó kọ ipa Miranda Barlow nínú eré Black Sails ni ọdún 2014.
Ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Barnes sì ìlú KwasZulu-Natal, ó sì gboyè nínú ìmò Dramatic Art láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Witwatersrand.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Barnes tí kópa nínú orísìírísìí eré bíi Egoli, 7de Laan, Binnelanders, Scandal!, Sorted, Suburban Bliss ati S.O.S.
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fiimu
Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1993 | Where Angels Trend | - | |
2002 | Borderline | Karen Kendler | |
2003 | Hoodlun & Son | Celia | |
2004 | Critical Assignment | Laura | |
2009 | Surviving Evil | Rachel Rice |
Telefiisionu
Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1996 | Suburban Bliss | ||
1997-2000 | Egoli | Adele de Bruyn de Koning | |
2006-2007 | Jozi-H | Jocelyn Del Rossi | |
2011 | The Sinking of the Laconia | Mary Bates | |
2009-2013 | Scandal! | Donna Hardy | SAFTA Winner—Best Actress in a TV Soap[2] |
2014-2016 | Black Sails[3][4] | Miranda Barlow | |
2017 | Outsiders | Moregon | |
2019 | NCIS | Sarah/Sahar |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Donna Hardy". e.tv. 1974-04-26. Archived from the original on 19 June 2013. Retrieved 13 May 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ http://www.etv.co.za/news/2013/04/15/louise-barnes-life-after-scandal
- ↑ "Black Sails" (in en). EW.com. Archived from the original on 2015-01-06. https://web.archive.org/web/20150106075136/http://www.ew.com/ew/article/0,,20779458,00.html.
- ↑ KpopStarz (2014-08-14). "'Black Sails' Season 2 Trailer And Release Date: Starz Bought Season 2 Of 'Treasure Island' Prequel Before Season 1 Aired [VIDEO"]. KpopStarz. Archived from the original on 2016-03-04. https://web.archive.org/web/20160304041057/http://www.kpopstarz.com/articles/104120/20140814/black-sails-season-2.htm.