Jump to content

Lucky Johnson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Lucky Johnson jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń sìn gẹ́gẹ́ bí Aṣojú Ìpínlẹ̀ tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò Isuikwuato ní Ile-igbimọ aṣofin ìpínlè Abia . [1] [2] [3]