Jump to content

Lucy Ameh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lucy Ameh
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kẹfà 1980 (1980-06-12) (ọmọ ọdún 44)
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjirià
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásitì Amodu Bello
Iṣẹ́Òṣeré àti oníṣòwò

Lucy Ameh /θj/ (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹfà ọdún 1980) jẹ́ òṣeré àti oníṣòwò ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣeré nínú ere Braids on a Bald Head ní ọdún 2010.[1]

Ayé àti èkọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Lucy ní Kaduna ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹfà ọdún 1980. Ó bẹ̀rẹ̀ si ń ṣe eré ìtàgé nínú ilé ìjọsìn rẹ̀ nígbà tí ó sì jẹ́ ọmọdé. Ó kàwé gboyè ní NTA TV college, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ B.Sc nínú ìmò Mass Communication ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò, Zaria kí ó tó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ diploma in Law ní Yunifásítì ìlú Jos.[2]

Lucy bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe eré ìtàgé láti ìgbà èwe rẹ̀, ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré kí ó tó kópa nínú eré 'Queen of Zazzau', èyí tó mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mọ́.[3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Why You Should Kneel To Thank Anyone That Gives You Food In Nigeria — Actress Lucy Ameh". Daily Post Naija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 July 2022. Archived from the original on 29 March 2023. Retrieved 3 August 2022. 
  2. "Lucy Ameh: I hope the industry go through an overhaul, get proper". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 13 November 2021. Archived from the original on 3 August 2022. Retrieved 3 August 2022. 
  3. "Filming ‘Amina’ was a different experience – Lucy Ameh". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 27 November 2021. Retrieved 3 August 2022. 
  4. Ataro, Ufuoma (14 November 2021). "Movie Review: 'Amina' fails to hit bull’s eye". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 August 2022.