Jump to content

Prótókólù Lusaka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Lusaka Protocol)

The Prótókólù Lusaka, ni ìwé àdéhùn ti ìjọba Angola àti àwọn agbógun UNITA jijo towosi ni Lusaka, Zambia ni October 31, 1994, lati mu opin ba Ogun Abele Angola nipa gbigba ohun ijagun kuro lowo UNITA ati jije ki won o kopa ninu ijoba Angola lati mu isowopo olomoorile-ede wa. Awon mejeji jo towobowe ijanuogun gege bi igbese protokolu na ni November 20.[1]


  1. Vines, Alex. Angola Unravels: The Rise and Fall of the Lusaka Peace Process, 1999. Human Rights Watch.