Ìpéjọlunipa ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Lynching in the United States)
Ìpéjọlunipa (Lynching), ìwà pípéjọ pa ènìyàn láìsí ìdájọ ṣẹlẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láyi òpin ọ̀rúndún 18k títí dé ìgbà àwọn ọdún 1960. Ìpéjọlunipa ṣẹlẹ̀ gidigidi ni Apágúúsù Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti 1890 dé àwọn ọdún 1920, pẹ̀lú 1892 bíi ọdún tó ṣẹlẹ̀ jùlọ. Bákannáà, ìpéjọlunipa náà tún wọ́pọ̀ ní Agbègbè Ìwọ̀òrùn.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |